sentence stringlengths 14 109 | root stringlengths 2 6 | root_meaning stringlengths 3 64 ⌀ |
|---|---|---|
Bí ògiri Adio kò bá lanu, aláàmù Olusegun kò lè wọ ibẹ | ALÁÀMÙ | LIZARD |
Ire ni ojú owó n rí | Ire | Goodness |
Agbe sise kò yẹ ọmọlúwàbí rárá | AGBE | BEGGING |
Fi ÒRÍ pa ara rẹ kí ó má dàn-án | ÒRÍ | Shea Butter |
Mo rán ọmọ ní Obì àti orógbó | Obì | Colanut |
ọkọ́ jẹ́ ọ̀kan gbóògì nínú irinṣẹ́ àgbẹ̀ | Ọkọ́ | Hoe |
Ìjì tí ó jà ní alẹ́ àná ni agbára púpọ̀ | ÌJÌ | STORM |
Igi Osè kì í pẹ́ gbabode | OSÈ | A TYPE OF TREE |
Adesoji kò mọ iye owó tí ó kó pamọ́ mọ́ | IYE | NUMBER |
Àwọn olórin fi ijo sí, nígbà tí àwon oníbàtá dá wọn lára mi | Bàtá | a type Drumbeat |
Rí dájú pé o fọ ẹsẹ̀ kí o to wọlé | Ẹsẹ̀ | leg |
Ọwọ́ Bukola ni orógùn yìí tí kán sí méjì | ORÓGÙN | TURNING STICK, TURNER |
Opamade nífẹ̀ẹ́ sí ilà kẹ́kẹ́ ju àbàjà lọ | KẸ́KẸ́ | A PECULIAR FACIAL MARK |
Kabiyesi náà fí olá jiyọ̀ láàfin | Ọlá | wealth |
Gbogbo nkan há gágá fún Adé bíi ọjọ mẹta sẹyìn | Gágá | Tightly |
Yorùbá ní ìṣẹ́ kìí déédé ṣẹ bí o bá nídìí | Ìṣẹ́ | poverty |
Ọ̀mọ tí wọ́n lò lára ilé náà kòtó | Ọ̀mọ | A builder of wall |
Ọbẹ̀ ẹyìn dun jẹ iyán | Ẹyìn | palm tree fruit |
Mọ fe ra agbọ̀n ní ọjà ní ọlà | Agbọ̀n | Basket |
Ilà àbàjà ni won nkọ ni ilu Òwu | Ilà | triber mark |
Ogun kò dà bí iyán àti ẹ̀kọ́ | OGUN | WAR |
àpò ògùn apa Ẹ̀fọn dára láti máa fi sùn | Ẹ̀FỌN | MOSQUITO |
Máa ṣọ́ra láti bá Àbẹ̀ọ́ rìn nítorí ìwà | ASA | TALKATIVE |
Kẹkẹ tí ba gbogbo igba oko Solape jẹ́ | KẸKẸ | A GRUB WHICH MAKES HOLES IN CALABASH |
Ago mélòó ni ìdíje náà yóò bẹ̀rẹ̀ | AGO | CLOCK |
Ẹ bá mi rántí mú Awò mi bọ̀ nínú yàrá | AWÒ | SPECTACLE |
Fi Abó bu omi wá | Abọ́ | plate |
Ajá tí yóò sọnù kòní gbọ́ fèrè ọlọ́dẹ | Ajá | Dog |
Ìtẹ́ Ọ̀kẹ́rẹ́ náà járọ̀ nígbà tó jábọ́ | Járọ̀ | To break a fall |
Ìyá mi nílò Àyè tí ó gbòòrò fún ọjà wọn | ÀYÈ | SPACE |
Ìwó tí o ni ilẹkùn ti o ni kọ́kọ́rọ́ ni wọ́n ki oríkì àwọn ọmọ ìpínlẹ̀ naa | Ìwó | A town in osun state |
Mo lọ sí ọjà ni àná | Àná | yesterday |
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ta ẹyẹ ní ỌFÀ | Ọfà | catapult |
Mo fẹ́ lọ sí ilé ìtọ̀ láti to | Ìtọ̀ | Urine |
Ẹkún ìyàwó jẹ́ ọ̀kan gbóògì nínú àṣà yorúbá | Ẹkún | Cry |
Ọrẹ títa nínú oṣù lamulana dára púpọ̀ | ỌRẸ | ALMS |
Abẹ́ ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ni ìlú ìbàdàn wà | Ìlú | Village |
Kunle àti Ṣọla jọ kanko asọ àrán lo s'ode | Àrán | cloth |
Ọ̀rẹ́ mi àtàtà ni Kolawole àti Taofiki | Ọ̀RẸ́ | FRIEND |
Ẹyin akẹ́kọ̀ọ́ mi, ẹ rí dájú pé ẹ ka àwọn ewì yín dáadáa, Ẹ̀RÁN ni ó jẹ fún yín ooo | Ẹ̀rán | Something not to forget |
Inú kò gbọ́dọ̀ bí Baba aláwò, kí ó fi ajá bọ ifá | IFÁ | god of divination |
Ẹ̀KỌ̀ ẹlẹ́kọ̀ ni ẹ̀gbà ẹlẹ́gbà | Ẹ̀KỌ̀ | Abandoned |
Ọmọ ìlú Ọ̀la ni alaga tuntun ni ìjọba ìbílẹ̀ rẹ | Ọ̀LÀ | a town in Osun State |
Ilá pele ti Ṣọla ko ni aburo baba re fi dá mọ̀ | Ilà | triber mark |
Ẹ̀yà ni o ma ń fi ìran kan yàtọ̀ sí òmíràn | Ẹ̀YÀ | Tribe |
Ayò ọlọpọlọ gbáà ni ayò ọlọ́pọ́n | AYÒ | GAME |
À-kúkú-bí, ó sàn jù kí ènìyàn bí ọ̀dẹ̀ ọmọ lọ | Ọ̀DẸ̀ | IMBECILE |
idanilẹkọ yóò wáyé lọla nipa aràn | Aràn | worm |
Àwọn ọmọ ile-iwe náà bu ọ̀wọ̀ fún akẹgbẹ won to se dáadáa nínú ìdíji oníléjilé | Ọ̀wọ̀ | honour |
ọ̀gọ̀rọ̀ àwọn odẹ ló sun rárà ní bi igbeyawo | Rárà | A type of song/elegy |
Àwọn ìkókó yìí kò mọ ọtun yàtọ̀ sí òsì rárá | ÌKÓKÓ | BABY |
Igun ilé ni a kò àdá wa sí | IGUN | CORNER |
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ fi orin dà wa lára yá | Orin | music |
Òkú tí o kú ni a sin sí itẹ́ | Itẹ́ | Burial ground |
Ba mi já orín bọ̀ wá ní oko | Orín | chewing stick |
Ogún ti àwọn òbí Tade fi sílẹ̀ fún un titó lo aye | OGÚN | INHERITANCE |
Ẹ̀yin wo lẹ n pariwo níbè yẹn | Ẹ̀yin | Those |
Iṣẹ igbà hìhun ni Ishọ̀la yan láàyò | Igbà | rope use to climb palm tree |
Ọ̀lẹ ni Àlàmú kòlè kọ igba ebè l'oko | Ọ̀le | Lazy |
okó ẹṣin yìí gùn ju àwọn èyí tí ó wà nínú ọgbà lọ | Okó | penis |
Ẹ̀ya ti o wà ní ara rẹ̀ kọ jà ohun ti a lè fẹ nu sọ | Ẹ̀ya | Tears |
Kòsí ohun ti gaga ọwọ̀ kan le se | Gaga | A piece |
Ọ̀kan lára àwọn ìdí náà buru gán | Idì | Eagle |
Igi ìgbá yìí so ní ọdún yìí púpọ̀ | Ìgbá | locus |
Ọmọ tí ó jí gègé mi nìyí | JÍ | STEAL |
Kì bá dára kí o sá fún àwọn ọdaju ènìyàn yẹn | SÁ | RUN AWAY |
Ǹjẹ́ kìí se aago mẹ́ta ni ẹ padà fi ìpàdé sí | AGO | CLOCK |
Akin lo járọ́ ti Ṣọla pa fún wa | Járọ́ | To expose a lie |
Ohun tí Adé se fún àbúrò rẹ̀ burú gan | Ohun | Thing |
Gbiyanju kí o lọ sí ilé ìwòsan fún iwò ojú | Iwò | spectacle |
iná jó ilé náà | Iná | Fire |
Oyebisi fẹ́ dé ọ̀dọ̀ àyò rẹ̀ lókè odò | ÀYÒ | FAVORITE |
kí olùwà fi ìtọ́ ràn wá lọ́wọ́ | Ìtọ́ | Guide |
Bàbá ran ọmọ ní ike ní ọjà | Ike | plastic |
Iná ko jẹ ki awọn adiẹ náà gbádùn | Iná | Lice |
Òdo ni Àlàmú gba nínú idanwo to ṣe | Òdo | Zero |
ọ̀fà jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìlú tí o gbajúgbajà ní ìpínlẹ̀ kúárà | ọ̀fà | city in kwara state |
Ojo rọ̀ ni ọsẹ to kọjá | Ọsẹ | Week |
Adura Bukọ́la gbà nígbà tí wọn fi ire rẹ le lọwọ | Ire | Goodness |
Mo nífẹ̀ẹ́ láti ra Àgò mìíràn fún àwọn adìẹ mi | ÀGÒ | THE MOBILE CAGE FOR CHICKEN |
ỌSÀN tí o wà ní Orí igi náà ti pọ́n | Ọsàn | Orange |
Adukẹ́ gún iyán nínú odó | Odó | Mortal |
Kí ojú máa ríbi gbogbo ara lò gun rẹ̀ | Ara | Body |
ìwọ àti èkejì rẹ ẹ Pin ọsán yìí Àbò | Àbò | Half |
Èmi ati ìyàwó fẹ́ lọ sí bi ayẹyẹ ní ọ̀la | Ọ̀la | tomorrow |
Ẹ̀re akọni ọdẹ náà wà ní ẹnu ìloro ìlú wọn | Ère | Statue |
Mo dá arábìnrin náà ni oko owò | Owò | business |
Eku ilé kò ṣe gba ojú bọ̀rọ̀ fún | EKU | RAT |
Ike yìí mọ rẹwà púpọ̀ | Ike | plastic |
Mo ṣe àkíyèsí wípé àwọn Àlàmú ma ń ní ìwà púpọ̀ | ÀLÀMÚ | A MALE NAME |
Nínú ìjànbá ọkọ̀ to waye gaga irun ori ẹnìkan kò jona | Gaga | A piece |
Dókítà òyìnbó tí gbà á ní ìmọ̀ràn pé kí ó wá gba abẹ́rẹ́ titanọọsi sí ojú egbò rẹ̀ láti dènà aburú ọjọ́ iwájú | EGBÒ | WOUND |
Ẹ bá mi pé ìyá ìkókó pé mo fẹ́ rí i | ÌKÓKÓ | BABY |
Ọgbọ̀n náírà ni mo ra ọsàn ẹyọ̀kan l'ọja | Ọgbọ̀n | Thirty |
ọbẹ̀ ọ́yọ́ máa dùn jẹ́ ẹ̀bà tútù | Ọ́YỌ́ | VEGETABLE |
Ṣọla ati awọn akẹgbẹ tó jọ kò ọ̀wọ́ rin, nígbà tí wọn jáde ile-iwe | Ọ̀wọ́ | Group/ Collectively |
Ìsàlẹ̀ ọrọ̀ a máa ní ẹ̀gbín ní ọ̀pọ̀ ìgbà | ỌRỌ̀ | WEALTH |
kínni ìdí tí Akin se n sá lọ? | Ìdí | Reason |
Iṣẹ ọsẹ ni ìyá àgbà n ṣe | Ọsẹ | Soap |
Fáṣítì ìjọba àpapọ̀ ti Ilé-Ifè dára púpọ̀ | IFẸ̀ | A TOWN IN OSUN STATE NIGERIA |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.