sentence stringlengths 14 109 | root stringlengths 2 6 | root_meaning stringlengths 3 64 ⌀ |
|---|---|---|
Ègún ìdílé kò ní sẹ lórí gbogbo wa | Ègún | Spell, curse |
Mo fún ọmọ ní igba náírà lá ti fi jẹun | Igba | two hundred |
Ẹnití a bá torí tiẹ̀ pa adìẹ, iwe ló máa ń jẹ́ | IWE | GIZZARD |
Àná ni ọjọ́ìbí mi | Àná | yesterday |
Inú òkùn ni mo bá Sọlápé nigba ti mo dé ilé wọn | Òkùn | Darkness |
Ọkàn lara ọjà to gbajugbaja ni ọjà Gbági ni ìlú Ìbàdàn jẹ | Ọjà | market |
Bọọlu náà ti kọjá ìlà ki adari ayo to fan fere | Ìlà | line |
Ètò ìṣúná fún àwọn odi wà lára ohun tí ìjọba mẹnu bà | Odi | dump |
Ẹ̀yìn ni olukọ ti na akẹkọ náà | Ẹ̀yìn | Back |
Ogún àpò ẹ̀wà kò lé tó wa lò níbi ìnáwó òkú ìyá àgbà | OGÚN | TWENTY |
ìjọba kọ́ ilé ìwé ìgbàlódé sí ìlú Òdí | Òdí | A town in bayelsa |
Oṣù tó ń bọ̀, ní ọ̀wẹ̀ yóò kàn mí | Ọ̀wè | A COMPANY SUMMONED TO ASSIST ONE OF THEIR MEMBER IN MANUAL LABOR |
Ẹ̀sín tí wèrè yóò ṣe, kìí jẹ́ kí ó kú bọ̀rọ̀ | Ẹ̀SÍN | SHAME |
Pátákó yìí kò sí fún kíkọ ikọkukọ | PÁTÁKÓ | PLANT, BOARD |
Èṣù má ṣe mí, ọmọ ẹlòmíràn ni kí o ṣe | ÈṢÙ | DEVIL |
Ẹkùn jẹ́ ọ̀kan lára ẹranko tó rẹ wà | Ẹkùn | Leopard |
Ẹja nla ni ìwọ̀ ọmọ náà gbé | Ìwọ̀ | Hook |
Akinyemi se ọgbà fún àwọn ẹran rẹ̀ | Ọgbà | Garden |
Ogunleke mú ejò ọkà wá sí inú abúlé ni ÀYÈ | ÀYÈ | ALIVE |
Ọmọ tí ntà ÒRÍ kiri kọjá ní òwúrọ̀ | ÒRÍ | Shea Butter |
Àwọn agbófinró fi ìpá dára sí ọ̀daràn náà lára | ÌPÁ | KICK |
Ojú egbò náà nílò ìtọ́jú gidigidi | EGBÒ | WOUND |
Itan ni Mobolaji fi ṣèse níbi ìjàmbá ọkọ̀ | ITAN | THIGH |
Ìkokò ńlá kan wà ní agbègbè oko wa nígbà kan | ÌKOKÒ | WOLF |
Ẹṣin Ọba ti fi pátákò rẹ gbá akódà lẹ́nu | PÁTÁKÒ | HOOF |
Ìjì kìí jà, kí ó dà omi inú àgbọn nù | ÌJÌ | STORM |
Olùkọ́ náà fẹ́ràn láti máa mú Egba dání | ẸGBA | CANE |
A ní láti bẹ̀rẹ̀ díẹ̀ kí a lè rí ọ̀nà náà gbà | BẸ̀RẸ̀ | BEND |
Ara kìí ṣe òkúta ni awọn yorùbá wí | Ara | Body |
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mọ odi nítorí Àbò | Àbò | Security |
Ọ̀rọ̀ tí a jọ sọ ní àná, ó ti di ọ̀rọ̀ awo o | AWO | SECRET |
Àgbẹ̀ tí ó lọ sí oko tí kò mú ọkọ́ lọ́wọ́ eyín rẹ̀ ni yíò lò | Ọkọ́ | Hoe |
Adesola sá àsálà fún ẹbọra búburú náà | SÁ | RUN AWAY |
Àwọn Oladele pa ỌKÁ ńlá kan ní ọ̀sán yii | ỌKÁ | COBRA |
Díẹ̀ loku ki n tẹ ejò paramọ́lẹ̀ mọ́lẹ̀, nitori ọgba ni àwọ̀ rẹ̀ ati erupẹ ilẹ̀ | Ọgba | Equal |
Solape gbọ́dọ̀ dé ìlú Ọ̀yun ni kùtùkùtù ọlá | Ọ̀YUN | A TOWN IN KWARA STATE |
Igi osè pọ̀ nínú oko Baba bàbá mi | OSÈ | A TYPE OF TREE |
Wo ẹ̀gbẹ́ Ọ̀TÚN rẹ kí o gbé baagi rẹ | Ọ̀tún | right |
A ní láti sà àwọn ìdọ̀tí ẹ̀wà náà dáadáa | SÀ | PICK |
Aràn n yọ ọmọ náà lẹnu | Aràn | worm |
Ọ̀gá wa ti ń bọ̀ wá sí yàrá ikawe | Ọ̀GÁ | MASTER |
Àwọn Talabi ni ṣíṣe ni Ìpínlẹ̀ ògùn ni oṣù tó ń bọ̀ | ÒGÙN | A STATE IN NIGERIA |
Ìlú Ọ̀TÙN rẹwà púpọ̀ láti gbé | Ọ̀TÙN | A city in Ekiti |
Àrò yẹ nígbà tí Bọ́lá n dáná lọwọ, ọbẹ sì dànù | Àrò | stone meant for cooking |
Gbogbo àgbọn tí mọ rà ní ọjà lo tí bàjẹ́ | Àgbọn | coconut 🥥 |
Ìlú Ọ̀yun rọrùn láti gbé púpọ̀ | Ọ̀YUN | A TOWN IN KWARA STATE |
Ẹyẹ idì náà gbé ọmọ Adìẹ | Idì | Eagle |
Àwọn oníṣòwò ìkòkò a máa jèrè púpọ̀ ní ayé àtijọ́ | ÌKÒKÒ | LOCAL POT |
gbogbo igi afàrà inú oko baami tí dawo tán | Afàrà | Shingle wood |
olùkọ́ àgbà ra ọkọ̀ fún ìyàwó rẹ̀ | Ọkọ̀ | CAR |
Gbogbo ilé kí bàbá kú Àbò | Abọ̀ | welcome |
Ejò isán jẹ́ ejò olóró tí ó burú púpọ̀ | ISÁN | A TYPE OF SNAKE (WHICH LIKE SLEEPING) |
Láti le tesiwaju, a nílò ìfẹ́ aisẹtan láàárín wa | ÌFẸ́ | LOVE |
Àwọn agbábọ́ọ̀lù jẹ́jẹ̀ atilẹyin wọn fún akọ́nimọ̀ọ́gbá tuntun | Jẹ́jẹ̀ | To make a vow |
Ìkokò kì í fi eegun já afira | ÌKOKÒ | WOLF |
Kúnlé ra asọ fún àwọn Òbí rẹ̀ | Òbí | parent |
òkò tí a sọ mọ ọ̀pẹ ni ọ̀pẹ ṣọ mọ́ ni | Òkò | stone🪨 |
Ẹnití ó bá gbé ọkàn lé Ọlọhun, yóò ní ìyè àìnípẹ̀kun | ÌYÈ | LIVE |
Ó gbọ́dọ̀ ṣe Ẹ̀rán orin náà dáadáa kí ó tó lè dán mọ ọ lẹ́nu | Ẹ̀rán | Something not to forget |
Bí èniyàn kò bá dé oko bàbá ẹnìkan kò le mọ̀ bí o ti fẹ̀ tó | Oko | farm |
Gbogbo ìlú lé arákùnrin náà sí ẹ̀yìn ìlú ní torí wípé iké tí o ní | Iké | hunchback |
Òní ni owo ọ̀yà yín yóò jẹ́ sísan | OWÓ | Ọ̀YÀ |
Ọmọ kékeré kan bú sí Ẹkún láàrín ojú ọ̀nà | Ẹkún | Cry |
Adekunle fẹ́ràn kí ó máa jẹun ní orí òró | ÒRÓ | STAND |
Àwọn ará ìlú feyikọgbon fẹ́ mọ ìdí ọrọ̀ Agbaakin ìlú naa | ỌRỌ̀ | WEALTH |
Ọta tán nínú ìbọn awọn olè náà ni wọn bá fi ẹsẹ fẹ́ ẹ | Ọta | Bullet |
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ eegún ló wà níbi ayẹyẹ ìfinijoyè | Eegún | masqurade |
igi oro ti wó lulẹ | ORO | A TYPE OF TREE |
Ìkà ni olópàá to yinbọn mo ọmọ náà | Ìkà | wicked |
Ipa wo ni ìwọ là kalẹ̀ fún ọjọ́ iwájú àwọn èwe | IPA | PATH |
ìlù bàtá ni wọn lù ni ọjọ́ìbí mi | Bàtá | a type Drumbeat |
Ara àwọn ìlú tí o jẹ́ gbaju gbaja ni ìlú ìwó jẹ́ | Ìwó | A town in osun state |
Kò sí bí àna se kéré tó àna ni àna yíò ma jẹ | Àna | inlaw |
Ìkà ni Kunle ti o lẹ okuta mo ọrẹ rẹ | Ìkà | wicked |
Eku àgó náà tí lu Pakute | ÀGÓ | A TYPE OF RAT |
Ìlú Ọ̀yọ́ ni mo gbé dàgbà | Ọ̀YỌ́ | A STATE IN NIGERIA |
Bàbá aláwò sọ fún àwọn adigun jalè náà pé kí wọn lọ wa Osé Sango wá | OSÉ | A TOOL USED BY SANGO WORSHIPPERS |
Aya mi mọ iyán gún | Aya | Wife |
Bi ara kò bá rọ OKÙN ara kòlè rọ adiẹ | Okùn | Rope |
Àwo mẹ́jọ ni ìyá àgbà sọ wípé mo fọ nígbà tí mo wà ní kékeré | ÀWO | PLATE |
Ìjọba gbọ́dọ̀ maa san owó ọ̀yà àwọn òṣìṣẹ́ ni kété tí oṣù bá ti parí | OWÓ | Ọ̀YÀ |
Òjò tí ó rọ̀ ni àná tí ṣiṣẹ́ ìyè fún igi náà | ÌYÈ | LIVE |
Ṣé o lè tẹ́lẹ̀ mi de Ọ̀rẹ̀ ni Ọ̀tunla | Ọ̀RẸ̀ | A CITY IN ONDO STATE, NIGERIA |
ìyàwó tí wọ́n fẹ́ láìpẹ́ yìí ti bí ọmọ | Ọmọ | child |
Àìsàn ibà ni Ẹ̀fọn máa ń fà lára | Ẹ̀FỌN | MOSQUITO |
Ẹ gbé ẹrù náà sí Igun ilé ìdáná | IGUN | CORNER |
A nílò isan ni ori ọmọdé, kí a lè gba ibẹ fún ní abẹ́rẹ́ | ISAN | VEIN |
Isan méjì ni àwọn dókítà sọ pé ó já ní ọwọ́ ọmọ ganfe naa | ISAN | VEIN |
Adewolu ni àyò bàbá rẹ̀ | ÀYÒ | FAVORITE |
Ẹfọ̀n kúrò ní ẹran àfi Pakute pa | ẸFỌ̀N | BUFFALO |
Ọmọ bíbí ilú ìlá ni oga ọlọ́pàá lorile ede Nigeria tẹlẹ rí | Ìlá | a town in Osun state |
Ilé ọlá dára púpọ̀ láti gbé | Ọlá | wealth |
Ọwọ́ tẹ awọn olè ti wọn n da ilu Ọ̀tà láàmú | Ọ̀tà | A town in Ogun State, Nigeria |
Ẹni tí ó ni èkù lo ni ọ̀bẹ | ÈKÙ | CUTLASS/KNIFE HANDLE |
Ọpẹ́ tí ẹ dá yẹn kéré jọjọ | ỌPẸ́ | THANKS |
Ọ̀já kan ṣoṣo tí ìyá Ìbejí rà logo pọn àwọn ọmọ rẹ mẹrẹrin | Ọ̀já | Rapper to mount baby |
ọdún kẹta nìyí tí mo ti ń lo ajọ̀ mi | AJỌ̀ | SIEVE |
Igbà lo já ti akọ̀pẹ náà se kan | Igbà | rope use to climb palm tree |
Mo Sùn ní èbá ọ̀nà lànà | Sùn | Sleep |
Mọ gbàgbé láti ranmi létí ní ọ̀la | Ọ̀la | tomorrow |
Subsets and Splits
No community queries yet
The top public SQL queries from the community will appear here once available.