path audioduration (s) 1.19 11.2 | text stringlengths 12 116 |
|---|---|
Ìbọn ló bàá l’ẹ́sẹ̀. | |
Ọwọ́ mi ni kẹ́ẹ wò. | |
Òṣogbo ni wọ́n ti gbé àgbò náà bọ̀. | |
Ọ̀rúnmìlà nìkan ló gbọ́ ohùn ẹnu Olódùmarè yékéyéke. | |
Gbénró ló pe ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn. | |
Bí babaláwo náà ṣẹ̀ gba ibẹ̀ kọjá ni. | |
Ọmọ bàba olówó ni mí. | |
Abẹ́ igi Ọ̀dán ni wọ́n ti máa ń sábà pa ààlọ́. | |
Ilẹ̀kùn yàrá Tádé ti bàjẹ́. | |
Òǹkà Yorùbá ni mo kọ́ àwọn ènìyàn níbi ìpàdé àná. | |
Désọ́lá lọ wẹ̀ lódò. | |
Bàbá àgbà, ṣé ẹ ti jí? | |
Bísí jẹ́ ìyàwó kejì. | |
Àwọn Yorùbá kò fi ọwọ́ yẹpẹrẹ mú ọrọ ọmọ bíbí láwùjọ. | |
Ẹlẹ́nu bótobòto, a ó ma wírú yó ma wírù. | |
Mú aṣọ kúrò nílẹ̀. | |
Wọ́n so ẹran mọ́ ‘lẹ̀ lọ́jọ́ iléyá. | |
Ikú Olóògbé Dúró Ládiípọ̀ dun gbogbo ìlú. | |
Arómáṣọdún bímọ ọkùnrin làǹtilanti. | |
Òwe lẹ ó máa pa, ẹ ò ní pànìyàn. | |
Àpò ṣaka ni wọ́n kó gbogbo ẹrù wọn sí nígbà tí wọ́n lọ sí ìrìn àjò náà. | |
Ẹranko ti Jíbádé fẹ́ràn jù ni akọ ajá. | |
Kí a máa dán ìgbàgbọ́ wa wò. | |
Wọ́n mú ọmọ náà ṣeré. | |
Àwàdà ni a fi bẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀ náà. | |
Ẹnikẹ́ni tí ìwọ́ bá ní ipá láti ṣe ìrànlọ́wọ́ fún òun ni ẹnìkejì re. | |
Láfún ni a jẹ. | |
Mo ra ìwé mẹ́ta níbẹ̀. | |
Ìsọkúsọ Àmọ́dù ti pọ̀ jù. | |
Kí ló dé tò ń pè mí lánàá? | |
Orí àdògán ni wọ́n ti ń rokà. | |
Òòrùn ò tíì wọ̀ tán. | |
Kí ló dé tí àwọn kan ma ń bínú tí wọ́n bá̀ ṣàpèjúwe wọn gẹ́gẹ́ bí i è̀nìyàn sísanra? | |
Mo ní’fẹ̀ẹ́ bí o ṣe máa ń rẹ́rìn-ín. | |
Mo fẹ́ ra ẹyin bíbọ̀. | |
Ilé epo náà tóbi, ẹ̀bá ọ̀nà ló wà. | |
Owó ni kókó o. | |
Ojúbọ òrìṣà ni owó náà wà. | |
Àdúrà gbogbo òbí ni kí ọmọ wọ́n ṣ’oríire. | |
Ra ọtí tàbí ẹmu fún wa. | |
Yòrùbá bọ̀ wọ́n ní, “Kò sí bí a ó ṣe se ebòlò tí kò ní rungbẹ́.” | |
Kò ye ká máa sọ̀rọ̀ ṣàkàṣàkà torí a ò mọ ẹni tó lè ranni lọ́wọ́. | |
Kò rí oorun sùn lálẹ́ àná; èyí múu bínú. | |
Ọ̀gọ̀njọ́ òru ni àwọn eléyi tún pariwo. | |
Ó ti jẹ gbèsè púpọ̀. | |
Mọ fẹ́ràn ẹlẹ́dẹ̀. | |
Ó ti sá lọ, ọ̀rọ̀ náà kọjá ohun tí agbára rẹ̀ ká. | |
Àdùkẹ́ ti sanra ju ọjọ́ orí rẹ̀ lọ. | |
Mi ò nífẹ̀ẹ́ sí àti máa jẹ ìgbá, mo nífẹ ọsàn dípò rẹ̀. | |
Ṣe o ti rí ìdí tí kò fi lè tètè ní ọ̀rẹ́kùnrin. | |
Ṣé wàá jẹ́ bàbá àwọn ọmọ mi? | |
Orí ẹní ni mo sùn mọ́jú. | |
Màá máa wá wò yìn nílé láìpẹ́. | |
Ọ̀la ni ìsimi ọlọ́jọ́ gbọọrọ máa bẹ̀rẹ̀. | |
Ọláwùnmí jẹ́ ẹni tí ó ní ìrẹ̀lẹ́. | |
Olórí ilé aṣòfin wà ní agbègbè náà. | |
Gbogbo èyí ni mo ti ṣe fún ẹ, ǹjẹ́ ìwọ́ lè ṣe èyí fún mi? | |
Kòkòrò ààrùn tí ò gbóògun ti pọ̀ ní ìlú yìí. | |
Dọ́kítà sọ pé àwọn oní gbèsè òun ò tí sanwó. | |
Bá mi bu omi mímu wá nínu ìkòkò tó wà l'ábàáwọlé. | |
Ṣé o wà ní oríi Twitter? | |
Bàbá àti màmá ti lọ sí òde òkú àwọn Ṣeun. | |
Dáre ni akọ̀wé ẹgbẹ́ akọrin inú ìjọ wa. | |
Kò s’ẹ́ni tó mọ Ifá tán. | |
A ti gé igi kan lulẹ̀. | |
Ìyẹn náà ni pé àwọn ìlú kékèké nínú igbó yìí náà máa ń lo iná ìjọba. | |
Ẹyẹlé funfun kìí bí dúdú. | |
Ẹranko burúkú kan ló pa àwọn ẹran náà jẹ. | |
Mo ò dára nínú eré bọ́ọ̀lù gbígbá. | |
Lọ mú àtòrì wá l’ẹ́yìn ilẹ̀kùn. | |
Imú ọmọ ìkókó náà dọ̀tí. | |
Ìsàlè àpótí ni màmá máa ń kó àwọn aṣọ olówó iyebíye wọn sí. | |
Ilé ìfowópamọ́ yapa nì agbègbè Adéọlá Ọdẹ́kù. | |
Ìdíje ńlá gbáà ni àwọn ẹgbẹ ọdẹ ń fi Ìrèmọ̀jé Ògún ṣe. | |
Nígbà tí ènìyàn tó burú báyì bá ń ronú kó jáwọ́ nínú ìwà ìbàjẹ́, mélòómélòó ìwọ. | |
Àkìtàn ọ̀hún wà níwájú. | |
Alágídí l’ọmọ náà, ó fi jọ ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ni. | |
Èyí já sí pé, gbogbo ìmọ̀ pátá ló ń bẹ nínú ifá. | |
Ọ̀la ni ọdún iléyá ní Ìjẹ̀bú Òde. | |
Yà sí apá ọ̀tún tí o bá dé Òpópónà Ìṣẹ́ri. | |
Àgbàlá Bàbá Fọlákẹ́ ni àwọn ọmọ ti máa ń ṣ’eré ní ìrọ̀lẹ́. | |
Ṣùgbọ́n, mo já èso kan lórí igi. | |
Nínú gbogbo ilé ìwòsàn agbègbè yìí, ti ọ̀nà òpópónà òkìtìpupa ni ó dára díẹ̀. | |
Mo ti lo rí ọ̀gá mi kan lorí ọ̀rọ̀ ọ̀hún. | |
Àǹkárá olójúméje ni Ṣaléwá wọ̀. | |
Folúkẹ́ ti múra tán kí àwọn àlejòo rẹ̀ tó dé. | |
Ọmọ yìí ò ní àpọ́nlé kankan rárá. | |
Ṣé o lè yá mi l’ówó títí di ìparí oṣù. | |
Jọláadé kìí yẹ́ ṣerépá. | |
Adéògún ti d’ọjà nù. | |
Èròjà tí a fẹ́ fi se ọbẹ̀ kò tí ì pé o. | |
Ó le kú, ìjà ọ̀rẹ̀. | |
Ọkàn mí wúwo púpọ̀. | |
Ẹ jẹ́ ká sùn díẹ̀, ṣùgbọ́n oorun ò kùn mí. | |
Bíléèdì gé ọmọ náà ní’ka. | |
Mí ò ṣeré o; òdodo ọ̀rọ̀ ni. | |
Tí mo bá ti wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ Ọlájùwọ́n, ara rẹ kì í lélẹ̀. | |
Fi ara balẹ̀ ṣá, má ṣè’jọ̀gbọ̀n. | |
Eéwo mú mi lábẹ́ etí. | |
Àwọn Àbẹ̀gbé yóò tó dé láti Ísírẹ́lì ní ọ̀sẹ̀ méjì sí òní. |
End of preview. Expand in Data Studio
- Downloads last month
- 9