Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
audio
audioduration (s)
2.17
53.3
user_id
stringclasses
16 values
language
stringclasses
1 value
text_id
stringlengths
8
8
source_text
stringlengths
29
393
duration
float64
2.17
53.3
recorded_at
stringdate
2025-11-25 20:00:18
2026-01-14 10:04:11
original_sample_rate
int64
48k
48k
silence_ratio
float64
0
0.47
snr_db
float64
30
57.6
speech_rate
float64
0.37
9.66
volume_db
float64
-39.99
-12.02
split
stringclasses
1 value
english_text
stringlengths
34
339
mapping_key
stringlengths
7
7
Y001
yoruba
YTR_0001
Ní àwọn agbègbè kan ní àwọn ìgbèríko Bujumbura, olúìlú Burundi, ẹ̀kún-omi máa ń ṣẹlẹ̀ lóòrèkóòrè tí ìjọba kò sì rí ọ̀nà-àbáyọ alálòpẹ́ ṣe síi.
11.89
2025-11-25 20:00:18
48,000
0.39
32.07
3.45
-39.99
train
In some neighbourhoods on the outskirts of Bujumbura, the capital of Burundi, floods occur regularly without the government finding a sustainable solution.
TR_0001
Y001
yoruba
YTR_0002
Ó ba ni lọ́kàn jẹ́ pé, èyí kìí ṣe ìgbà àkọ́kọ́ tí wọ́n máa kọjú irúfẹ́ àjálù bẹ́ẹ̀: ìdúnkòokò omíyalé ní Gatumba bẹ̀rẹ̀ ní ọdún 2016.
10.83
2025-11-28 19:59:03
48,000
0.31
31.02
4.43
-37.29
train
Unfortunately, this is not the first time they have had to face such a disaster: the threat of flooding in Gatumba began in 2016.
TR_0002
Y001
yoruba
YTR_0003
Àwọn ọ̀ràn tí wọ́n ń wáyé léraléra náà ti dá ìṣẹ̀lẹ̀ ìṣínípò tipátipá sílẹ̀ fún àwọn ará agbègbè náà.
6.17
2025-11-25 20:06:42
48,000
0.24
33.82
5.02
-38.49
train
These repeated crises have created a situation of forced displacement for the local population.
TR_0003
Y001
yoruba
YTR_0004
Àwọn èèyàn kan ń gbé ní ẹ̀bá-ọ̀nà náà, a ṣẹ̀ṣẹ̀ kúrò ní àwọn àyè ìpéjọ náà ni.
3.43
2025-11-25 20:07:59
48,000
0.43
38.64
4.66
-39.73
train
Some people live along the roads, we recently left the gathering sites.
TR_0004
Y001
yoruba
YTR_0005
Àwọn yòókù péjò sí àyè tí ó wà fún ìgbà díẹ̀ ní àwọn ìgbèríko ibi tí omíyalé wà, wọ́n ń dúró de ibòmíràn tí wọn yóò tèdó sí ṣùgbọ́n tí àwọn aláṣẹ kò tíì fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀.
11.05
2025-11-25 20:09:21
48,000
0.27
32.84
4.43
-38.88
train
Others gather in transit sites on the outskirts of the flooded area, waiting to be resettled in a location yet to be determined by the authorities.
TR_0005
Y001
yoruba
YTR_0006
Ọ̀pọ̀ àwọn agbègbè tí ẹ̀kún omi ya wọ̀ ni wọ́n wà ní ìtòsí Rusizi National Park.
5.75
2025-11-25 20:10:42
48,000
0.36
32.82
4.17
-39.39
train
A large number of the flooded neighbourhoods are located near the Rusizi National Park.
TR_0006
Y001
yoruba
YTR_0007
Níbi ààyè ìdúró náà ni etídò Rusizi èyí tí a kò dáàbò bò lati pèsè òrùlé fún àwọn ilé tó wà lágbègbè yìí nìkan; àmọ́ fún ìyípadà ojú ọjọ́ náà, eléyìí tí ó ń ṣokùnfà kí òjò rọ̀ nígbà tó wùú, níkẹyìn, àìní ìmọ̀ nípa àwọn àgbègbè tí ó ṣeé ṣe kí omíyalé ti ṣẹlẹ̀ tí kò dára fún ibùgbé ọmọniyàn.
20.63
2025-11-25 20:14:53
48,000
0.32
32.2
3.63
-36.64
train
In the docks are the banks of the Rusizi River which are not protected to shelter the homes in this area; but also climate change, which alters seasons and causes rainfall at any time; and, finally, the lack of information on flood-prone areas unsuitable for human habitation.
TR_0007
Y001
yoruba
YTR_0008
Omi náà gbé ohun èlò ilé ìdáná, ibùsùn, àwọn ìwé àwọn ọmọdé, àti àwọn ohun èlò mìíràn lọ.
7.23
2025-11-25 20:20:27
48,000
0.36
37.25
3.18
-39.5
train
Kitchen equipment, bedding, children’s notebooks, and other necessities were taken away by the water.
TR_0008
Y001
yoruba
YTR_0009
Wọ́n dáwọ́ ìrìn-àjò afẹ́ dúró nítorí pé àgbàrá ti ya bo ọ̀nà tí ó lọ sí àyè ìgbafẹ́ náà.
5.69
2025-11-25 20:22:44
48,000
0.28
32.44
4.39
-33.72
train
Tourism is suspended because the flood has blocked access to the park.
TR_0009
Y001
yoruba
YTR_0010
Nibaruta tún wí pé àwọn èèyàn Mushasha I àti II tó kù yóò kó lọ sí àwọn agbègbè mìíràn.
6.95
2025-11-25 20:29:57
48,000
0.35
36.69
3.6
-39.71
train
Nibaruta also stated that the remaining population of Mushasha I and II will be relocated to other areas.
TR_0010
Y001
yoruba
YTR_0011
Wọ́n máa ṣe àwọn iṣẹ́ yìí ní àsìkò ẹ̀ẹ̀rùn tí ó ń bọ̀ tí yóò sì ná wọn ní USD 324 mílíọ̀nù, gẹ́gẹ́ bí fídíò yìí ṣe ṣàlàyé ní Kirundi.
9.93
2025-11-25 20:32:16
48,000
0.29
30.32
4.63
-38.37
train
These works will be carried out during the next dry season and will cost USD 324 million, as explained in this video in Kirundi.
TR_0011
Y001
yoruba
YTR_0012
Cyclone Idai ń ṣe àfihàn ìnílò fún àwọn ẹgbẹ́ adóòlà-ẹ̀mí láti máa ronú nípa ẹ̀mí àwọn ẹranko ní àkókò irú àwọn àjálù ìwọ̀n yìí.
9.37
2025-11-25 20:38:45
48,000
0.27
32.05
4.27
-37.83
train
Cyclone Idai highlights the need for rescue teams to consider the lives of animals during disasters of this magnitude.
TR_0012
Y001
yoruba
YTR_0013
Láti bíi ọ̀sẹ̀ mélòó sẹ́yìn, àwọn ẹranko ìgbẹ́, àwọn ẹranko oko, àwọn ẹranko odò àti àwọn ẹran ọ̀sìn ni àjálù náà ti ṣe àkóbá fún.
10.39
2025-11-25 20:39:50
48,000
0.4
38.84
3.85
-38.67
train
Over the last few weeks, wild animals, farm animals, aquatic animals and pets were affected by the disaster.
TR_0013
Y001
yoruba
YTR_0014
Nígbà tí àwọn iṣẹ́ àkànṣe ìgbàlà ní àfojúsùn lórí ẹ̀mí ọmọnìyàn, wọ́n kìí sábà ka àwọn ohun tí kìí ṣe ènìyàn kún débì kí wọ́n ronú wọn.
10.33
2025-11-25 20:42:07
48,000
0.29
30.47
6
-38.91
train
While rescue missions focus on human life, non-human beings are rarely accounted for and considered.
TR_0014
Y001
yoruba
YTR_0015
Ẹ jẹ́ kí á gbà pé ìdáhùn wa kò lágbára tó, ẹ kọ́ ẹ̀kọ́ kí ẹ sì ṣe àtúnṣe.
6.43
2025-11-25 20:51:45
48,000
0.41
33.43
3.89
-33.1
train
Lets agree that our respone is weak, learn and improve.
TR_0015
Y001
yoruba
YTR_0016
Àwọn ajàfitafita fún àwọn ẹranko ń gba àwọn ènìyàn níyànjú láti rántí má fi àwọn ẹranko sílẹ̀ lásìkò ìṣílọ tàbí ìyọnikúrò nínú ewu kí wọn ó sì rántí láti ṣàwárí àwọn ẹranko tí wọ́n ṣèṣe tàbí tí ara ń ni lẹ́yìn ìkọlù.
15.91
2025-11-25 20:55:45
48,000
0.32
32.37
3.83
-36.62
train
Animal activists encourage citizens to remember not to leave animals behind during evacuation or rescue operations and remember to look for injured and distressed animals in the aftermath.
TR_0016
Y001
yoruba
YTR_0017
Àwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì dúró lórí pé ìyípadà ojú ọjọ́ jẹ́ ohun pàtàkì tí ó ń fa ìjì yìí àti omíyalé tí ó ń ṣẹlẹ̀ káàkiri tí wọ́n ní bíi ọ̀sẹ̀ díẹ̀ sẹ́yìn ní gúúsù ilẹ̀ Adúláwò.
12.17
2025-11-25 20:59:31
48,000
0.29
31.77
3.7
-35.85
train
Scientists insist that climate change played a major role in creating this cyclone and the widespread flooding witnessed over the last few weeks in southern Africa.
TR_0017
Y001
yoruba
YTR_0018
Àyípadà ojú-ọjọ́ yóò túbọ̀ mú kí àwọn ìjì bíi èyí ní agbára kí ó sì burú síi.
6.31
2025-11-25 21:00:50
48,000
0.36
34.42
3.96
-36.32
train
Climate change will continue to make storms like this one more severe and intense.
TR_0018
Y001
yoruba
YTR_0019
Ní ọ̀pọ̀ ìgbà, àwọn ìjàm̀bá ajẹmágbègbè wọ̀nyìí máa ń ní ipa lórí àwọn tí wọn kò fi bẹ́ẹ̀ lọ́wọ́ nínu ohun tí ó ń ṣokùnfà àyípadà ojú-ọjọ́.
10.83
2025-11-25 21:06:17
48,000
0.39
35.66
3.69
-36.49
train
Often, these environmental disasters impact those who have done the least to cause climate change.
TR_0019
Y001
yoruba
YTR_0020
Wọn ò tíì ṣe àgbéyẹ̀wò ìwọ̀n ìparun àti ipa tí ó ní lórí ẹ̀mí èèyàn, ẹranko àti ọ̀gbìn gan ní pàtó.
7.97
2025-11-25 21:07:29
48,000
0.39
32.31
3.89
-35.76
train
The real extent of the devastation and the impact on human, animal and plant life is yet to be assessed.
TR_0020
Y001
yoruba
YTR_0021
Ní Mozambique, wọ́n ti fẹ́rẹ̀ pa ìlú Beira run tán pátápátá.
4.97
2025-11-25 21:08:44
48,000
0.4
35.58
3.62
-33.01
train
In Mozambique, the city of Beira has been nearly entirely wiped out.
TR_0021
Y001
yoruba
YTR_0022
Ó kéré tán èèyàn 89 ni wọ́n ti papòdà ní Zimbabwe nìkan, tí ìbẹ̀rùbojo sì wà pé ó lè jù bẹ́ẹ̀ lọ, ní Manicaland ti ẹkùn Chimanimani, tí ó wà ní kìlómítà 406 ní ìlà-oòrùn olú-ìlú Zimbabwe, Harare, bí ìjì alágbára kan tí ó bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ Ẹtì ṣe ti gbé àwọn ilé àti àwọn afárá lọ.
26.55
2025-11-25 21:13:51
48,000
0.41
31.13
3.88
-36.2
train
At least 89 people have died in Zimbabwe alone, amid fears of a higher figure, in Manicaland's Chimanimani district, located 406 kilometers east of Zimbabwe's capital, Harare, as homes and bridges were swept away by a tropical storm that began on Friday.
TR_0022
Y001
yoruba
YTR_0023
Àjọ Àkójọpọ̀ Àwọn Orílẹ̀-èdè ní orílẹ̀-èdè Zimbabwe sọ pé ó lé ní 8000 àwọn ènìyàn ní wọ́n ti lùgbàdì omíyalé ní àwọn agbègbè ìlà oòrùn orílẹ̀-èdè náà.
11.39
2025-11-25 21:19:21
48,000
0.34
32.4
4.74
-33.77
train
The United Nations in Zimbabwe said that more than 8,000 people have been affected by the flooding in the eastern parts of the country.
TR_0023
Y001
yoruba
YTR_0024
Ìjì náà bẹ̀rẹ̀ láti Indian Ocean ó sì sokunfà òjò oníjì líle tó bẹ̀rẹ̀ ní Mozambique lọjọ Igbe, tí atégùn ń fẹ́ pẹ̀lú eré tó tó kìlómítà 160 láàárìn wákàtí kan, èyí tí ó sì fàá kí ìgbì òkun ga tó mítà 9.
16.91
2025-11-26 01:50:02
48,000
0.3
31.07
5.14
-39.87
train
The storm originated in the Indian Ocean and led to a torrential rainstorm which commenced in Mozambique on Thursday, with wind speeds of about 160 kilometers per hour, reportedly causing ocean waves of up to 9 meters high.
TR_0024
Y001
yoruba
YTR_0025
Wọ́n ti rán àwọn ọlọ́pàá àti àwọn ológun lọ láti lè kó àwọn olùfarapa kúrò.
6.15
2025-11-26 01:51:07
48,000
0.35
33.26
4.06
-38.62
train
The police and military have been deployed to assist in the evacuation of victims.
TR_0025
Y001
yoruba
YTR_0026
Gẹ́gẹ́ bí ilé-iṣẹ́ ìjọba fún Ìwífún ṣe sọ, ilẹ̀ ti ń mọ́ kedere dáadáa tí èyí yóò sì ṣe ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ọkọ̀ òfurufú àwọn ológun ajàlófurufú láti kó ọ̀pọ̀ àwọn èèyàn kúrò.
12.21
2025-11-28 19:13:17
48,000
0.35
36.09
5.24
-36.28
train
Visibility, according to the Information ministry, has significantly improved and this will help airforce helicopters to evacuate more people.
TR_0026
Y001
yoruba
YTR_0027
Wọ́n ti já àwọn ọ̀nà, àwọn afárá àti àwọn tẹlifóònù báyìí tí ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ àwọn ilé sì ti di píparun.
8.43
2025-11-26 01:56:14
48,000
0.41
35.4
4.39
-39.77
train
Roads, bridges and telephones are currently cut off and hundreds of homes destroyed.
TR_0027
Y001
yoruba
YTR_0028
Olùdarí agbègbè fún International Red Cross (IRC) ti Zimbabwe tó ń jẹ́ Paolo Cernuschi sọ pé àwọn ikọ̀ IRC ní Zimbabwe ń gbìyànjú láti kàn sí àwọn tí cyclone ṣe ìpalára fún àmọ́ àwọn ohun amáyedẹrùn tó bàjẹ́ náà pọ̀ tó bẹ́ẹ̀ gẹ́ tí àwọn ikọ̀ nàá kò ráyé dé Chimanimani tàbí Chipinge.
23.17
2025-11-26 01:59:04
48,000
0.34
33.61
3.93
-37.99
train
Country director for the International Red Cross (IRC) Zimbabwe Paolo Cernuschi said the IRC teams in Zimbabwe are trying to reach communities affected by the cyclone but the infrastructure damage is severe and the teams couldn't reach Chimanimani or Chipinge.
TR_0028
Y001
yoruba
YTR_0029
"Àwọn àtúnṣe ọ̀nà ní wàràǹsesà ń lọ lọ́wọ́lọ́wọ́ torí náà a máa tún gbìyànjú rẹ̀ ní òwúrọ̀."Cemuschi fèsì.
9.43
2025-11-26 02:00:40
48,000
0.31
34.05
5.94
-38.89
train
“Urgent road repairs in progress so we will try again in the morning,” said Cernuschi.
TR_0029
Y001
yoruba
YTR_0030
Òṣìṣẹ́ kan tí ó ń ṣisẹ́ pẹ̀lú Ẹ̀ka tí ó ń Mójútó Ojú Ọjọ́ sọ pé ìjì líle náà ti dínkù púpọ̀ ó sì ti sún láti ìlà-oòrùn lọ sí àwọn agbègbè àríwá ìlà-oòrùn ti orílẹ̀-èdè Zimbabwe.
13.83
2025-11-26 02:02:22
48,000
0.36
32.94
4.48
-38.45
train
An official with the Meteorological Services Department said that the cyclone has weakened greatly and shifted from eastern to northeastern areas of Zimbabwe.
TR_0030
Y001
yoruba
YTR_0031
"Wọ́n ṣe àkọsílẹ̀ tí ó tó 200 mìlímita omi òjò ní Chipinge [tí ó wà ní ìlà-oòrùn orílẹ̀ èdè Zimbabwe], 118 mìlímita ní àríwá Chipinge, àti 102 mìlímita ní Buhera [gúúsù ìlà oòrùn Orílẹ̀ èdè Zimbabwe]," òṣìṣẹ́ ìjọba náà ni ó sọ bẹ́ẹ̀.
20.77
2025-11-26 02:15:34
48,000
0.38
30.01
3.9
-36.37
train
“Up to 200 millimeters of rainfall was recorded in Chipinge [located in eastern Zimbabwe], 118 millimeters north of Chipinge, and 102 millimeters in Buhera [southeastern Zimbabwe],” said the official.
TR_0031
Y001
yoruba
YTR_0032
Ìjà ilẹ̀ ti di aáwọ̀ níbi tí ó ti ń ṣẹlẹ̀ pé ó fẹ́rẹ̀ tó mẹ́jọ nínú mẹ́wàá àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Malagasy ni wọ́n ń gbé nínú ìṣẹ́ tí wọ́n sì gbáralé ilẹ̀ fun ìjẹ-ìmu àti ìwàláàyè wọn.
14.31
2025-11-26 02:17:43
48,000
0.31
31.73
5.31
-36.73
train
Land claims have become more disputed within a context where almost eight in 10 Malagasy citizens live in poverty and depend on land for their livelihoods and survival.
TR_0032
Y001
yoruba
YTR_0033
Ọ̀rọ̀ The Toliara Sand jẹmọ́ iṣẹ́ ìwakùsà tí iléeṣé Australia kan tó ń jẹ́ Base Resources jẹ́ agbáterù rẹ̀ láti máa ṣe ìwakùsà ilmenite àti àwọn ohun àlùmọ́nì(rutile, zircon and leucoxene) ní agbègbè gúsù ìwọ̀-oòrùn Madagascar.
20.79
2025-11-26 02:19:40
48,000
0.37
33.18
3.56
-35.01
train
ZR: The Toliara Sands case concerns the mining project majority-financed by Australian company Base Resources for mining ilmenite and precious heavy metals (rutile, zircon and leucoxene) along the southwest coast of Madagascar.
TR_0033
Y001
yoruba
YTR_0034
Láti October 2014, àwọn ìjíròrò ìdásí ọ̀rọ̀ àwùjọ ní àwọn agbègbè tí iṣẹ́ àkànṣe ìwakùsà ṣe ìpalára fún àti ìlu Toliara ti fún ọ̀pọ̀ àwọn àwùjọ tó wà léti omi ni ànfààní láti le kọ̀ jálẹ̀ sí níní ọwọ́ nínú iṣẹ́ àkànṣe yìí.
19.83
2025-11-26 02:23:50
48,000
0.4
33.02
4.34
-34.71
train
Since October 2014, public consultations in the areas affected by the mining project and in the town of Toliara have given several waterside communities the opportunity to voice their rejection of this project.
TR_0034
Y001
yoruba
YTR_0035
Ní àtẹ̀lé ìpinnu [Ìgbìmọ̀ náà], àwọn àwùjọ tí ó kàn pé ara wọn jọ láti tún ṣe ẹ̀rí ìtakò wọn sí àwọn Ìkéde Ohun Èlò (DUP) fún ìfẹ́ Toliara Sands, pàápàá àwùjọ apẹja Vezo, tí wọ́n fi ẹ̀hónú wọn hàn dáadáa ... ní àkókò ìwọ́de gbogboogbò ní ọjọ́ 27 oṣù Agẹmọ, ọdún 2018.
24.63
2025-11-26 06:21:36
48,000
0.39
31.06
3.94
-38.11
train
Following [the Council's] decision, the affected communities mobilized to reaffirm their opposition to the Declarations of Public Utility (DUP) in favor of Toliara Sands, particularly the Vezo fishing community, who robustly voiced their opinions … during a public demonstration on July 27, 2018.
TR_0035
Y001
yoruba
YTR_0036
Ò ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ilé-iṣẹ́ láti jà fún ẹ̀tọ́.
4.29
2025-11-26 06:22:19
48,000
0.36
32.93
4.19
-35.63
train
GV: You work with many organizations to defend rights.
TR_0036
Y001
yoruba
YTR_0037
Dájúdájú ìfẹ́ òṣèlú tí àwọn ìjọba ní láti tẹ́tí sí àti láti ṣàkíyèsí ohun tí àwọn àwùjọ kéréjé fẹ́ ló má sọ nnkan tí yóò ṣẹlẹ̀, tí ìfààyè sílẹ̀ fún àwọn aráàlú láti sọ èrò ọkàn wọn àti pé ó ṣeé ṣe kí ìdásí àwọn àlábáṣepọ̀ ilẹ̀ òkèèrè lè fún ogún mọ́ ijoba láti mú ìfẹ́ wọn ṣẹ.
22.31
2025-11-26 06:25:34
48,000
0.38
34.03
4.39
-35.29
train
ZR: The determining factor is definitely the political will of the government to listen and pay attention to the voice of local communities, while the increased awareness of public opinion and intervention from international partners could heighten pressure on governments so that this political will becomes effective.
TR_0037
Y001
yoruba
YTR_0038
Gbogbo ènìyàn ní wọ́n lè fi ìdúró wọn hàn ní ọ̀nà tí ó tọ́ lójú wọn - fún àpẹẹrẹ, ọ̀pọ̀ lè kọ̀wé sí ààrẹ tuntun láti pè fún fífa igi le DUP fún àǹfààní Toliara Sands.
12.91
2025-11-26 06:27:32
48,000
0.38
35.43
4.03
-35.81
train
Everyone can show their solidarity in the way that seems most appropriate to them — for example, many can write to the new president to ask him to cancel the DUP in favor of Toliara Sands.
TR_0038
Y001
yoruba
YTR_0039
Ó sọ fún wa nípa àwọn àfojúsùn ètò náà àti àwọn àṣeyọrí rẹ̀ ní oṣù Ọ̀wẹ̀wẹ̀ ọdún 2011.
8.89
2025-11-26 06:29:22
48,000
0.37
33.35
4.83
-35.56
train
She told us about the objectives of the programme and its achievements in September 2011.
TR_0039
Y001
yoruba
YTR_0040
Láti ìgbà náà, àwọn èsì oríṣiríṣi àwọn ìwádìí yóò dà gẹ́gẹ́ bíi èyí tí ó ń fi ìdí àwọn àbájáde rere wọ̀nyí múlẹ̀, èyí tí yóò fi àyè sílẹ̀ fún àwọn ìlànà tuntun láti jà tako ìtànkálẹ̀ AIDS.
12.89
2025-11-26 06:32:39
48,000
0.32
33.03
3.41
-35.01
train
Since then, the results of various studies would seem to confirm these positive results, giving way to new approaches in the fight against the AIDS epidemic.
TR_0040
Y001
yoruba
YTR_0041
Ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn orílẹ̀ èdè tí a ti ṣiṣẹ́, àjàkálẹ̀ ti dáwọ́ dúró, àti pé ní àwọn orílẹ̀ èdè kan à ń rí àdínkù nínú iye òǹkà àwọn ọ̀ràn tuntun.
10.63
2025-11-26 06:34:06
48,000
0.39
31
3.76
-36.94
train
In most of the countries we work in, the epidemic has stabilised, and in some countries we are even seeing a reduction in the number of new cases.
TR_0041
Y001
yoruba
YTR_0042
Ǹjẹ́ o lè ṣe àlàyé bí a ṣe ṣe àwọn àṣeyọrí bẹ́ẹ̀?
4.31
2025-11-26 06:34:48
48,000
0.38
30.37
5.56
-33.55
train
GV:Could you explain how we achieved such positive results?
TR_0042
Y001
yoruba
YTR_0043
Ṣe àdínkù ti bá iye ọ̀ràn ní àwọn orílẹ̀-èdè tí ètò DREAM wà?
4.81
2025-11-26 06:36:03
48,000
0.3
34.1
3.32
-35.54
train
GV: Is there a reduction in the number of cases in all the countries where there is the DREAM programme?
TR_0043
Y001
yoruba
YTR_0044
A ti rí àwọn èsì tí wọ́n dára gan ní Malawi, Kenya àti Tanzania.
5.29
2025-11-26 06:36:53
48,000
0.35
36.48
4.91
-34.57
train
PG: We have had particularly good results in Malawi, Kenya and Tanzania.
TR_0044
Y001
yoruba
YTR_0045
Fún àpẹẹrẹ, ní Malawi ìdá àwọn èèyàn tí àjàkálẹ̀-àrùn náà ṣe àkóbá fún ti kúrò ní 15% lọ sí 11.5% láàárín ìwọ̀nba ọdún.
11.99
2025-11-26 06:40:30
48,000
0.44
33.56
4.67
-34.93
train
For example, in Malawi the percentage of people affected by the epidemic has gone from 15% to 11.5% in just a few years.
TR_0045
Y001
yoruba
YTR_0046
Iye àwọn èèyàn náà kéré tí àjàkálẹ̀-àrùn náà kò sì fi bẹ́ẹ̀ tàn káàkiri.
5.79
2025-11-26 06:41:25
48,000
0.4
36.83
5.01
-32.49
train
PG: The population is small and the epidemic was not as diffused.
TR_0046
Y001
yoruba
YTR_0047
Ìjọba, ní àpapọ̀ pẹ̀lú àwọn ilé iṣẹ́ tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ ní orílẹ̀ èdè náà, tí DREAM wà lára wọn, wọ́n fèsì daada sí àjàkálẹ̀ náà, ní èyí tí ó ń jẹ́ kí ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn ènìyàn ṣe ìtọ́jú àìlera láàárín ọdún díẹ̀.
14.17
2025-11-26 06:45:24
48,000
0.36
31.45
4.16
-35.47
train
The government, together with the organisations operating in the country, including DREAM, responded actively to the epidemic, putting thousands of people through therapy in just a few years.
TR_0047
Y001
yoruba
YTR_0048
Ètò DREAM ti ṣe àkójọ àwọn ẹgbẹ́ tí wọ́n ṣàbẹ̀wò sí àwọn agbègbè àwọn ìlú kan pàtó ní ilẹ̀ adúláwò láti ranwọ́ ìrànwọ̀ sí àwọn tí wọ́n lùgbàdì AIDS.
11.59
2025-11-26 06:46:28
48,000
0.34
33.18
4.14
-33.45
train
GV: The DREAM programme had put together mobile teams that visited areas of certain African cities to offer better assistance to the AIDS suffers.
TR_0048
Y001
yoruba
YTR_0049
Nípa ṣíṣe àbẹ̀wò sí àwọn ibi tí àwọn tí à ń tọ́jú ń gbé a máa nímọ̀ nípa àwọn ìṣòro náà daada, àti pé a le pawọ́ pọ̀ láti borí wọn.
9.59
2025-11-26 06:47:19
48,000
0.38
33.06
4.38
-33.51
train
By visiting the places where our patients live we can better understand the difficulties, the problems, and together we can work out ways to overcome them.
TR_0049
Y001
yoruba
YTR_0050
Láti ọdún díẹ̀ sẹ́yìn, pẹ̀lú ìtẹ̀síwájú láti ṣe ìwádìí àjẹsára kan, a tún ń ṣe ìwádìí bí ó bá ṣeéṣe láti ṣe àjẹsára aṣèwòsàn oníwọ̀nǹba, irú èyí tí ó lè mú ètò sójà ara àwọn èèyàn tí wọ́n ti ní ìkóràn tẹ́lẹ̀ dára síi tí wọ́n sì ń gba ìtọ́jú ìdènà kòkòrò apasòjà-ara.
17.75
2025-11-26 06:50:51
48,000
0.31
30.41
3.77
-35.64
train
PG: Over the last few years, as well as continuing to research a vaccine, we are also researching the possibility of making a partially therapeutic vaccine, one that can improve the immune system of people who are already infected and are receiving antiretroviral therapy.
TR_0050
Y001
yoruba
YTR_0051
ètò DREAM náà kò dá lé ṣíṣe ìdámọ̀ àti ìrànlọ́wọ́ fún àwọn tí wọ́n ní àrùn KASA nìkan.
7.27
2025-11-26 06:51:38
48,000
0.32
31.03
4.54
-35.67
train
GV: The DREAM programme does not limit itself to only identifying and helping HIV-positive people.
TR_0051
Y001
yoruba
YTR_0052
Lórọ̀ mìíràn a sọ fún àwọn ènìyàn ní àwọn ìlú tí a ti ní àwọn ìpìlẹ̀ nípa HIV, nípa ìdènà àti ìtọ́jú rẹ̀ àti nípa ẹ̀tọ́ àwọn tí wọ́n ní HIV.
14.83
2025-11-26 06:58:03
48,000
0.28
33.09
4.25
-18.44
train
In other words we inform people in the countries where we haves bases about HIV, about its prevention and treatment and about the rights of HIV-positive people.
TR_0052
Y001
yoruba
YTR_0053
Ní àwọn orílẹ̀-èdè kan ẹgbẹ́ àwọn èèyàn tí wọ́n ń dojú ìjà kọ ẹ̀gàn náà àti fún ẹ̀tọ́ sí ìtọ́jú tí pọ̀ yíká DREAM.
9.03
2025-11-26 06:59:27
48,000
0.13
30.01
4.54
-18.51
train
In some countries associations of people who fight against the stigma and for the right to treatment have developed around DREAM.
TR_0053
Y001
yoruba
YTR_0054
À ń gbìyànjú agbára wa láti pèsè àwọn ìnílò tí ó ṣe gbọmọgbọmọ sí àwọn èèyàn.
5.45
2025-11-26 07:02:58
48,000
0.11
32.61
5.32
-16.6
train
We try as much as possible to meet the most urgent needs of the population.
TR_0054
Y001
yoruba
YTR_0055
Fún àpẹẹrẹ, ní àwọn ibùdó wa kan, àti fi òòfà omi sí bẹ̀ nítorí pé a ṣe àkíyèsí pé àwọn ènìyàn agbègbè náà kò ní àǹfààní sí omi mímu daada.
11.77
2025-11-26 07:05:57
48,000
0.12
30.99
5.18
-16.42
train
For example, in some of our centers, we have installed water pumps because we noticed that the people of the area did not have sufficient access to drinking water.
TR_0055
Y001
yoruba
YTR_0056
A ti ṣí àwọn ilè ìfún-ni-lóúnjẹ fún àwọn ọmọdé ní Mozambique (Maputo àti Beira) láti dènà àìjẹunkánú ní kékeré, èyí tí ó wọ́pọ̀ tí ó sì máa ń ní àtunbọ̀tán lórí ayé àwọn ọmọ àti dídàgbà wọn lápapọ̀.
16.19
2025-11-26 20:25:15
48,000
0.32
33.19
4.08
-39.57
train
On the other hand, in Mozambique (Maputo and Beira) and in Malawi we have opened feeding centres for children to fight against childhood malnutrition, which is very common and has serous consequences on the life and general development of the child.
TR_0056
Y001
yoruba
YTR_0057
Ojoojúmọ́ ní gbọ̀ngán yìí ni àwọn ọmọdé tó lé ní 500 ní wọn ń gba oúnjẹ tó tó oúnjẹ, tí ó péye.
7.13
2025-11-29 14:29:59
48,000
0.3
34.3
3.36
-36.1
train
Every day in these centres approximately 500 children receive a full, balanced meal.
TR_0057
Y001
yoruba
YTR_0058
A gbọ́ pé ètò náà tún ń pín oúnjẹ fún àwọn mọ̀lẹ́bí àwọn èèyàn tí wọ́n ní Ààrùn Ìsọdọ̀lẹ Àjẹsára.
9.65
2025-11-26 07:12:08
48,000
0.2
31.05
3.73
-18.05
train
GV: We heard that the programme also distributes food to the families of the people affected by AIDS.
TR_0058
Y001
yoruba
YTR_0059
Ní ọ̀pọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè ilẹ̀ Adúláwọ̀ àwọn èèyàn ń jẹ́yà nítorí àìsí oúnjẹ bí ó ti yẹ, tí àìrí oúnjẹ aṣaralóore jẹ́ sì ń mú ipa àrùn KASA búrẹ́kẹ́ síi.
11.55
2025-11-26 07:15:34
48,000
0.12
31.66
5.19
-17.72
train
In many African countries people suffer because of an unstable food supply, and malnutrition aggravates the effects of HIV.
TR_0059
Y001
yoruba
YTR_0060
A máa ń ṣe ìrànwọ́ rírí oúnjẹ aṣaralóore jẹ ní àwọn orìlẹ̀ èdè tí a ti ṣiṣẹ, àmọ́, a gbọ́dọ̀ jẹ́ kò di mímọ̀ pé ó nira láti rí àwọn olùbáṣiṣẹ́-rannilọ́wọ́ tí wọ́n lè jẹ́ kí a túbọ̀ máa ṣe èyí torí ìṣòro tó bá ọrọ̀ ajé.
15.59
2025-11-26 07:19:32
48,000
0.12
32.12
4.49
-17.2
train
We offer nutritional aid in all the countries where we work, however, it must be said that with the economic crisis it is becoming ever more difficult to find partners who will help and sustain us in this area.
TR_0060
Y001
yoruba
YTR_0061
Lọ́dọ̀ ti wa, DREAM tayọ ṣíṣe ìrànwọ̀ ètò ìlerá bí kìí ṣe pé ó tún jẹ́ ìrírí ara àti ẹ̀mí pàtàkì: a ti rí bí àwọn akitiyan àwọn eèyàn ṣe ń ṣokùnfà ìṣòkan àti bí a ṣe lè kojú ìṣòro tó wúwo, tí ó sì yí kádàrá ọ̀pọ̀ awọn eèyàn padà.
18.05
2025-11-26 20:26:16
48,000
0.33
30.55
4.27
-36.34
train
PG: For us DREAM is not only about offering medical aid but it is also an important human and spiritual experience: we have seen how uniting many people's efforts we can face problems that seem insurmountable, changing the destiny of many people.
TR_0061
Y001
yoruba
YTR_0062
Ọ̀rọ̀ ti ń lọ lábẹ́nú lórí ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò mìíràn pẹ̀lú àwọn olórí BRAVO!
5.61
2025-11-26 20:27:45
48,000
0.34
33.85
3.92
-33.66
train
Talks are underway for another interview with the leaders of BRAVO!
TR_0062
Y001
yoruba
YTR_0063
Àtẹ̀jáde ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò yìí wáyé ọpẹ́lọpẹ́ Marisa Petricca, tí ó ṣe àyẹ̀wò rẹ̀, tí ó sì ṣe ìrànlọ́wọ́ àkójọ àwọn ìtọ́kasí, àwọn àwòrán àti a fọ́nràn tí ó yẹ.
11.65
2025-11-29 14:31:17
48,000
0.3
35.93
4.03
-36.26
train
The publication of this interview was made possible thanks to Marisa Petricca, who reviewed it and helps gather appropriate references, photos and videos.
TR_0063
Y001
yoruba
YTR_0064
Ilé-iṣẹ́ wọn, HealthPhone, tí Nand Wadhwani jẹ́ olùdásílẹ̀ àti olùṣẹ̀dá rẹ̀, ń ṣẹ̀dá àwọn fọ́nràn ìlera tí wọ́n ti ṣe àkọ́gbàsílẹ̀ wọn sí orí àwọn ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ jákèjádò India.
14.89
2025-11-26 20:30:13
48,000
0.36
30.2
4.5
-34.72
train
Their organization, HealthPhone, which was founded and created by Nand Wadhwani, who creates health videos that are preloaded to phones throughout India.
TR_0064
Y001
yoruba
YTR_0065
Àwọn fọ́nràn aláfihàn ìtumọ̀ ti ń wà nípasẹ̀ dotSUB, ìkànnì aṣàfikún ìtumọ̀ sí fọ́nràn tí ó ń fààyè gba àfihàn ìtumọ̀ nínú fọ́nràn ní èdèkedè.
11.53
2025-11-26 20:31:20
48,000
0.32
35.25
4.16
-36.84
train
The subtitled videos are made available through the dotSUB, a video subtitling platform that allows for subtitling in any language.
TR_0065
Y001
yoruba
YTR_0066
Wọ́n ń jọlá pé púpọ̀ nínú àwọn ará Kenya tí n ní ẹ̀rọ àgbéká, tí wọ́n lò ó láti ṣe àwárí àtí ìdásílẹ̀ ìmọ̀ tó jẹ mọ́ ètò ìlera wọn
9.65
2025-11-26 20:33:02
48,000
0.29
32.67
4.35
-35.27
train
They are taking advantage of the fact that more and more Kenyans have access to mobile phones, who are using them to consume and create important information related to their health needs.
TR_0066
Y001
yoruba
YTR_0067
Iṣẹ́ àkànṣe kan tí à ń ṣiṣẹ́ lè lórí fún ilé iṣẹ́ aláìjẹmọ́ èrè jíjẹ kan tí ó fi orílè-èdè Kenya ṣe ibùjókòó yóò fún àwọn èèyàn ìgbèríko ní àǹfààní láti wo ìròyìn ìlera ní èdè Swahili lórí ẹ̀rọ alágbèéká wọn.
14.87
2025-11-26 20:41:26
48,000
0.35
31.58
4.37
-31.12
train
One project we are working on for a Kenya-based non-profit will give rural people the chance to access Swahili health information on their cell phones.
TR_0067
Y001
yoruba
YTR_0068
Ní ọdún àkọ́kọ́ rẹ̀, Translation Workspace ti ṣe àfikún iye àwọn ọ̀rọ̀ tí wọ́n ṣe ìtumọ̀ wọn ní ìlọ́po mẹ́fà (láti oṣù Ṣẹ́ẹ́rẹ́ ọdún 2011 sí oṣù Ṣẹ́ẹ́rẹ́ ọdún 2012).
12.45
2025-11-28 19:14:23
48,000
0.32
33.23
4.58
-36.2
train
In its first year, the Translation Workspace increased the amount of translated words six-fold (from January 2011 to January 2012).
TR_0068
Y001
yoruba
YTR_0069
Ojú ìwé kọ̀ọ̀kan ni Dr. James Heliman yóò ṣàyẹ̀wò fínnífínní, ẹni tí í ṣe olórí Wikimedia ní orílẹ̀ èdè Canada, láti ríi dájú pé pípéye ìlera wà, ṣáájú kí àwọn olóòtú láti Content Rules tó mu rọrùn.
15.43
2025-11-26 20:43:47
48,000
0.34
31.87
4.67
-35.9
train
Each page is thoroughly reviewed by Dr. James Heilman, the head of Wikimedia Canada, in order to ensure medical accuracy, before being simplified by a team of editors at Content Rules.
TR_0069
Y001
yoruba
YTR_0070
Báyìí, iṣẹ́ àkànṣe náà ń fi oríṣi àwọn èdè 25 ṣiṣẹ́ lọ́wọ́lọ́wọ́.
5.83
2025-11-26 20:44:37
48,000
0.3
34.08
4.29
-34.75
train
So far, the project is currently working with 25 different languages.
TR_0070
Y001
yoruba
YTR_0071
Ìráàyèsí orí Ayélujára kò dára tó bí kò bá sí ní èdè rẹ!
4.81
2025-11-26 20:46:19
48,000
0.35
38.14
4.99
-32.68
train
Access to the Internet is not much good if it's not in your language!
TR_0071
Y001
yoruba
YTR_0072
Ọdún 1999 ni tí Sherif Abdel-Azim padà wà ní Egypt lẹ́yìn tí ó parí ẹ̀kọ́ Ìmọ̀-ìjìnlẹ̀ nínú Ìmọ̀-ẹ̀rọ Ajẹmọ́ná mọ̀nàmọ́ná àti Ẹ̀rọ Kọ̀m̀pútà ní Canada.
11.65
2025-11-26 20:48:55
48,000
0.3
31.02
4.46
-36.86
train
It was the year 1999 and Sherif Abdel-Azim was back in Egypt after finishing a Ph.D. in Electrical and Computer Engineering in Canada.
TR_0072
Y001
yoruba
YTR_0073
Abdel-Azim àti àwọn akẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ pinnu láti ṣẹ̀dá ẹgbẹ́ ìṣàánú aláìforúkọsílẹ̀ tí ó ń jẹ́ Resala (Mission).
9.07
2025-11-26 20:51:22
48,000
0.37
34.13
3.42
-34.49
train
Abdel-Azim and his students decided to set up an informal charity group called Resala (Mission).
TR_0073
Y001
yoruba
YTR_0074
Lẹ́yìn ọdún kan, ọ̀kan nínú àwọn akẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ dábàá kí wọ́n kọ́ ilé àwọn ọmọ aláìníyàá kan.
6.37
2025-11-26 20:52:30
48,000
0.39
34.92
4.86
-36.37
train
One year later, one of his students suggested they should build an orphanage.
TR_0074
Y001
yoruba
YTR_0075
Nínú oṣù Ramadan ní ọdún tó kọjá (2007), Resala ní èròńgbà láti gba aṣọ àlòkù tó tó ẹgbẹ̀rún 100 lọ́wọ́ àwọn eèyàn ní Egypt nípasẹ̀ àwọn ẹ̀ka rẹ̀ 7 tó wà ní Cairo àti ẹ̀ka 2 ní Alexandria.
13.87
2025-11-26 20:54:29
48,000
0.3
33.71
4.69
-35.39
train
During the month of Ramadan last year (2007), Resala aimed at collecting 100 thousand pieces of used clothes from people in Egypt through its 7 branches in Cairo and 2 branches in Alexandria.
TR_0075
Y001
yoruba
YTR_0076
Ìwọ̀nba ẹgbẹ̀rún kan aṣọ ìtọrẹ tí ó kù ni a ó tà ní owó pọ́ọ́kú fún àwọn aláìní ní gbogbo agbègbè ilẹ̀ Egypt nípasẹ̀ ìpàtẹ ọjà ọlọ́jọ́-mẹ́ta tí yóò wáyé ní nítòsí ilé wọn.
11.75
2025-11-29 14:32:16
48,000
0.3
37.05
3.57
-35.71
train
The rest of the one million pieces of donated clothes will be sold with very low prices to needy people in poor districts all over Egypt through small 3-day exhibitions held near their homes.
TR_0076
Y001
yoruba
YTR_0077
Iye owó ọ̀kọ̀ọ̀kan aṣọ àlòkù náà yàtọ̀ bẹ̀rẹ̀ láti bíi sẹ́ǹtì 50 àti $1 tí iye owó tí ó pọ̀ jù sì jẹ́ $3.
10.65
2025-11-26 20:57:24
48,000
0.39
32.84
4.22
-35.03
train
Prices for each piece vary around 50 cents and $1 with a maximum of under $3 for the most expensive used clothes pieces.
TR_0077
Y001
yoruba
YTR_0078
Ó fún wọn ní ìmọ̀lára pé wọn ra aṣọ náà pẹ̀lú owó wọn
3.85
2025-12-08 07:16:33
48,000
0.29
35.11
4.67
-37.55
train
It gives them the feeling they are buying the clothes with their own money.
TR_0078
Y001
yoruba
YTR_0079
Àwọn kan ní àwọn ìwé láti ọ̀dọ̀ ìjọba ilẹ̀ Italy èyí tí ó gbà wọ́n láàyè láti dúró ní Europe fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ oṣù.
7.63
2025-11-26 20:58:56
48,000
0.25
33.92
4.59
-34.04
train
Some had papers from the Italian government which allowed them to stay in Europe for several months.
TR_0079
Y001
yoruba
YTR_0080
Láàárín wákàtí 72, ìdá kan nínú ìdá mẹ́ta àwọn àjúfù láti rue Botzaris 36 ni ó pòórá, àwọn ọlọ́pàá kúrò ní ilé náà aṣojú ilẹ̀ òkèèrè fún orílẹ̀ èdè (Tunisia) sì gba ilé náà padà.
15.39
2025-11-26 21:05:43
48,000
0.26
31.69
4.87
-36.1
train
Within 72 hours, a third of the documents from 36 rue Botzaris disappeared, the police evacuated the building and the (Tunisian) ambassador reclaimed possession of the building.
TR_0080
Y001
yoruba
YTR_0081
Lẹ́yìn tí wọ́n kó rue Botzaris tí iye wọn jẹ́ mẹ́rìndínlógójì, àwọn olóṣèlú kọ̀ọ̀kan - yàtọ̀ sí MP ẹ̀ka ìjọba Ardèche French, Pascal Terrasse- ni wọ́n ti gbìyànjú láti bèèrè nípa àwọn ọmọ ìlú Tunisia tí wọ́n ń ye ibi ìṣeré Butters Chaumont lọ́wọ́ lọ́wọ́.
20.31
2025-11-26 21:07:54
48,000
0.33
32.54
3.94
-37.34
train
Since the evacuation of 36 rue Botzaris, few polititians – aside from the MP of the Ardèche French constituency, Pascal Terrasse – have bothered to enquire about the Tunisians who are currently surviving in Buttes Chaumont Park.
TR_0081
Y001
yoruba
YTR_0082
Ojú rẹ̀ jọ ti aláàárẹ̀, bí ó ṣe ń dá rìn láàárín àwọn afẹ̀hónúhàn ní gbọ̀ngàn Tahrir.
7.13
2025-11-26 21:09:40
48,000
0.35
32.94
4.49
-35.84
train
He looked very ill, walking alone among the protestors in Tahrir square.
TR_0082
Y001
yoruba
YTR_0083
Lẹ́yìn tí mo bì wọ́n, mo ríi pé ìlú Mansoura ni wọ́n ti wá tí wọ́n sì kópa nínú "Ìjà Ràkúnmí" náà.
7.57
2025-11-26 21:10:31
48,000
0.39
42.08
3.3
-36.84
train
After asking them, I found out that they came from Mansoura city and participated in the “Camel Battle”.
TR_0083
Y001
yoruba
YTR_0084
Wọ́n bá àtíbàbà náà ní òfo ní òwúrọ̀.
3.29
2025-11-26 21:11:12
48,000
0.32
32.36
3.64
-32.56
train
They found the tent empty in the morning.
TR_0084
Y001
yoruba
YTR_0085
Ìtàn yìí wà fún gbogbo ènìyàn tí kò yé pé ìdájọ́ jẹ́ nǹkan tí ó ṣe pàtàkì, gẹ́gẹ́ bíi àánú - tí kò bá tún ṣe pàtàkì jù bẹ́ẹ̀ lọ, bíi irú tí ààrẹ tí wọ́n yọ.
11.03
2025-11-26 21:12:51
48,000
0.31
32.8
5.17
-37.27
train
This story is for everyone who does not understand that justice is a very important value, exactly like mercy – if not more important, in case of the ousted president.
TR_0085
Y001
yoruba
YTR_0086
Ó sọ fún mi: "Wọ́n ti pa ọmọkùnrin mi, èmi nàá sì fẹ́ kú gan, gẹ́gẹ́ bíi akíkú-akíkanjú, bíi tiẹ̀.
8.01
2025-11-26 21:14:11
48,000
0.4
34.07
4.74
-38.84
train
He told me: “They killed my son, and I want to die too, as a martyr, like him.
TR_0086
Y001
yoruba
YTR_0087
Láti ìgbà tí rògbòdìyàn ti ń ṣẹlẹ̀ ní Libya, ọ̀pọ̀ àwọn asásàálà ni wọ́n ti gba ibodè tí ó wà láàárín Tunisia àti Libya kọjá.
8.35
2025-11-26 21:15:23
48,000
0.31
31.09
4.55
-32.71
train
The border between Tunisia and Libya has seen a massive influx of refugees since the uprising in Libya began.
TR_0087
Y001
yoruba
YTR_0088
Ó fẹ́rẹ̀ tó àwọn èèyàn 75,000 ni wọ́n sá fún rògbòdìyàn ní Libya lọ sí Tunisia, láti ọjọ́ 20 oṣù Èrèlé, tí ìrètí sì wà pé ọ̀pọ̀ yóò tún kún wọn.
12.41
2025-11-26 22:35:14
48,000
0.34
31.21
4.83
-37.51
train
Up to 75,000 people have fled the violence in Libya to Tunisia, since February 20, and even more people are expected.
TR_0088
Y001
yoruba
YTR_0089
IFRC ti fi fọ́nràn yìí láti ọwọ́ Ras Jdir síta ní ọjọ́ 1 oṣù Ẹrẹ́nà.
7.67
2025-11-26 22:37:10
48,000
0.46
34.56
3.39
-34.96
train
The IFRC have posted this video from Ras Jdir on March 1.
TR_0089
Y001
yoruba
YTR_0090
Àwọn ìpè láti wá gba àwọn asásàálà sílẹ̀ ní Ras Jdir ti ń tàn ká lórí àwọn ìkànnì ìbánidọ́rẹ̀ẹ́, àti pé wọ́n ti ṣètò fún àwọn ìpolongo láti gba ìrànwọ́ ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn.
12.69
2025-11-26 22:40:06
48,000
0.38
33.93
4.33
-38.22
train
Calls to come to the rescue of refugees in Ras Jdir have been spreading via social media, and campaigns to collect humanitarian aid have also been organised.
TR_0090
Y001
yoruba
YTR_0091
Àwọn yòókù, ní ẹ̀dùn ọkàn nípa wíwọlé lọ́pọ̀ owó sísan àwọn asásàálà fi àwọn ìnífẹ̀ẹ́sí orílẹ̀ èdè Tunisia sínú ewu ní àkókò ìyípadà tí ó jẹ́ ẹlẹgẹ́ láti ìgbà tí Ààrẹ Ben Ali ti sá kúrò ní orílẹ̀ èdè náà.
14.77
2025-11-26 22:42:44
48,000
0.29
34.55
4.2
-37.96
train
Others, were concerned that the massive flow of refugees pay put Tunisia's interests at risk during a very fragile transition period since the President Ben Ali fled the country.
TR_0091
Y001
yoruba
YTR_0092
ọ̀ràn asásàálà ní ras jdir jẹ́ ohun ìdúnkokò sí àlàáfíà tunisia – wọ́n nílò ìrànlọ́wọ́ àgbáyé ní kíákíá.
7.69
2025-11-26 22:43:36
48,000
0.27
33.1
4.55
-37.2
train
refugee crisis in ras jdir is another threat to tunisia's stability – international help needed quickly.
TR_0092
Y001
yoruba
YTR_0093
mubarak ni ó mọ̀ọ́mọ̀ ṣètò àìsí ààbò tí ó sì mú kí àwọn nǹkan má tòó láti mú ìpayà àti ìpínyà bá àwọn èèyàn #Jan25
8.65
2025-11-26 22:46:30
48,000
0.31
35.08
5.2
-39.07
train
the shortages just as the lack of security are deliberately planned and implemented by mubarak to strike fear and split the people #Jan25
TR_0093
Y001
yoruba
YTR_0094
@AlyaaGad Àwọn ènìyàn nílò oúnjẹ, owó àti ìrànlọ́wọ́ ajẹmọ́ṣègùn!
4.81
2025-11-26 22:47:14
48,000
0.26
37.45
4.57
-37.45
train
@AlyaaGad People need food, money and medical help!
TR_0094
Y001
yoruba
YTR_0095
@HB_1_2011: inú àwọn èèyàn dùn gidi ní egypt, tí wọ́n ò sì kọ̀ láti fi oúnjẹ àti owó rúbọ kí ìjọba tí ó wà níbẹ̀ fi lọ #jan25 #egypt.
8.19
2025-11-26 22:48:06
48,000
0.31
34.94
4.76
-39.84
train
@HB_1_2011: 618: people are euphoric in egypt, and willing to sacrifice with food and money so the regime would go #jan25 #egypt
TR_0095
Y001
yoruba
YTR_0096
Ṣùgbọ́n, ní ọdún 2002, Nelson Mandela fúnrarẹ̀ fi ọjọ́ yìí ṣe ìfilọ́lẹ̀ ìpolongo rẹ̀ lórí ìdènà àti ìmọ̀ nípa àrùn KASA àti Ìsọdọ̀lẹ Àjẹsára (KASA* Kòkòrò Apasójà Ara) ní àgbáyé, 46668.
16.11
2025-11-26 22:50:28
48,000
0.34
33.26
3.79
-38.88
train
In 2002, however, Nelson Mandela himself used this day to launch his global HIV/AIDS awareness and prevention campaign, 46664.
TR_0096
Y001
yoruba
YTR_0097
Àṣeyọrí àwọn ayeye àti ipolongo 46664 ní ọdún 2009 ló di ohun tí a mọ̀ sí “Mandela Day” lónìí, ọjọ́ kan tí àwọn eèyàn káàkirì àgbáyé yóò jọ̀wọ́ ìṣẹ́jú 67 láti fi lè sọ ayé di ibi ìrọ̀rùn fún mùtúmùwà.
18.19
2025-11-29 14:35:38
48,000
0.3
30.78
4.18
-34.78
train
In 2009, the success of the 46664 campaigns and celebrations evolved to what is now known as “Mandela Day”, a day in which people around the world dedicate 67 minutes to making the world a better place for all.
TR_0097
Y001
yoruba
YTR_0098
Wọ́n pinnu pé kò sí nǹkan kan tí ó tún lè yẹ ju kí wọ́n ṣe ayẹyẹ ọjọ́ ìbí Madiba ní ọdọọdún pẹ̀lú yíya ọjọ́ kan sọ́tọ̀ fún àwọn iṣẹ́ tí ó gbé ayé ṣe àti àwọn àjọ tí ó fi ń ṣàánú àti láti ríi dájú pé ohun tí ó fi sílẹ̀ kò parun.
16.29
2025-11-26 23:06:00
48,000
0.31
31.1
4.79
-39.53
train
It was decided that there could be nothing more fitting than to celebrate Madiba’s birthday each year with a day dedicated to his life’s work and that of his charitable organisations and to ensure his legacy continues forever.
TR_0098
Y001
yoruba
YTR_0099
Èyí yòó jẹ́ ọjọ́ ìfisọrí Nelson Mandela àkọ́kọ́, níwọ̀n ìgbà tí United Nations ti fi ofìn dèé ní November 2009 pé July 18 ni ọjọ́ tí wọ́n ya sọ́tọ̀ láti mọ rírì àwọn iṣẹ́ tó níi ṣe pẹ̀lú ẹ̀tọ́ ọmọniyàn.
16.55
2025-11-26 23:11:40
48,000
0.29
31.71
4.53
-38.24
train
It will be the first Nelson Mandela International Day, as the United Nations passed a resolution on the day in November 2009, declaring 18 July an international day set aside for humanitarian activities.
TR_0099
Y001
yoruba
YTR_0100
Ó jẹ́ ìgbà àkọ́kọ́ tí ilé iṣẹ́ náà ti ya àyájọ́ àgbáyé sọ́tọ̀ fún ẹnìkan, tí wọ́n fi ń ṣe ìdánimọ̀ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àmì ìrètí fún àwọn tí wọ́n ń ni lára tí wọ́n sì ti yà sọ́tọ̀.
10.65
2025-11-26 23:13:20
48,000
0.28
32.94
5.26
-38.54
train
It is the first time the organisation has dedicated an international day to an individual, recognising him as a symbol of hope for those who are oppressed and marginalised.
TR_0100
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
113